Follow Jesus Without Waiting for a More Convenient Time
Welcome to Day 275 of our journey with Jesus. Today, we think about how we will respond to Jesus. The main truth for today is this: Jesus calls us to follow him without indefinitely postponing our response. Let’s begin.
Current details of the journeyView the calendar, Episode and passage
Jesus in Action
Luke 9:51–62
Step 5 of 5
Decide how you will respond to Jesus.
Nígbà tí ọjọ́ àti gbà á sókè ń súnmọ́, ó pinnu láti lọ sí Jerusalẹmu. Ó sì rán àwọn ìránṣẹ́ lọ sí iwájú rẹ̀. Nígbà tí wọ́n sì lọ wọ́n wọ ìletò kan tí í ṣe ti ará Samaria láti pèsè sílẹ̀ dè é. Wọn kò sì gbà á, nítorí pé ó ń lọ sí Jerusalẹmu. Nígbà tí àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ Jakọbu àti Johanu sì rí i, wọ́n ní, “Olúwa wa, jẹ́ kí a pe iná láti ọ̀run wá, kí a sì pa wọ́n run, bí Elijah ti ṣe?” Ṣùgbọ́n Jesu yípadà, ó sì bá wọn wí. Lẹ́yìn náà Jesu àti àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ sì lọ sí ìletò mìíràn. Bí wọ́n ti ń lọ lọ́nà, ọkùnrin kan wí fún un pé, “Olúwa, Èmi ń fẹ́ láti máa tọ̀ ọ́ lẹ́yìn ní ibikíbi tí ìwọ bá ń lọ.” Jesu sì wí fún un pé, “Àwọn kọ̀lọ̀kọ̀lọ̀ ní ihò, àwọn ẹyẹ ojú ọ̀run sì ní ìtẹ́; ṣùgbọ́n Ọmọ Ènìyàn kò ní ibi tí yóò fi orí rẹ̀ lé.” Ó sì wí fún ẹlòmíràn pé, “Máa tọ̀ mí lẹ́yìn.” Ṣùgbọ́n èyí wí fún un pé, “Olúwa, jẹ́ kí èmi lọ sìnkú baba mi ná.” Jesu sì wí fún un pé, “Jẹ́ kí àwọn òkú máa sìnkú ara wọn, ṣùgbọ́n ìwọ lọ kí o sì máa wàásù ìjọba Ọlọ́run.” Ẹlòmíràn sì wí fún un pé, “Olúwa, èmi yóò tọ̀ ọ́ lẹ́yìn ṣùgbọ́n jẹ́ kí n kọ́kọ́ lọ dágbére fún àwọn ará ilé mi.” Jesu sì wí fún un pé, “Kò sí ẹni, tí ó fi ọwọ́ rẹ̀ lé ohun èlò ìtulẹ̀, tí ó sì wo ẹ̀yìn, tí ó yẹ fún ìjọba Ọlọ́run.”
Biblica® ní oore ọ̀fẹ́ láti lo Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní™ Ẹ̀tọ́ àdàkọ © 2009, 2017 Biblica, Inc. Biblica® Open Yoruba Contemporary Bible™ Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc. “Biblica” ni àmì ìdámọ̀ tí Biblica, Inc. fi sílẹ̀ ní United States Patent àti ní ilé iṣẹ́ tí wọ́n ti ń fúnni ní àmì ìdámọ̀. Gba àṣẹ kí o tó lòó. “Biblica” is a trademark registered in the United States Patent and Trademark Office by Biblica, Inc. Used with permission.
Jesus is moving toward Jerusalem with purpose. The question in this passage is not merely whether we admire His determination, but whether we will follow the One who speaks with such urgency.
Watch: Will You Follow Jesus Fully or Turn Back?
Watch the companion video, then continue reading to examine the biblical testimony in its full context.
Count the Cost Honestly.
Jesus does not lure followers with promises of comfort. He tells one man that the Son of Man has nowhere to lay His head. Serious discipleship begins without false advertising.
Stop Making Faith a Future Intention.
Two responses contain delay: first let me do this, first let me do that. Jesus’ words expose how easily “later” becomes a respectable way of saying “not now.”
Do Not Confuse Urgency With Impulsiveness.
Following Jesus is not emotional recklessness. His own journey is purposeful. The call is to undivided allegiance, not thoughtless enthusiasm.
Walk in His Direction.
The Savior has set His face toward the fulfillment of His mission. The fitting response is to stop negotiating for a safer, more convenient version of following and to take His call seriously now.
Consider this.
What response does Jesus require?
Take your next step
Follow the resolute Savior without treating discipleship as a permanently postponed intention.